Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 17-18

Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Bó O Ṣe Ń Wàásù Tó O sì Ń Kọ́ni

Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Bó O Ṣe Ń Wàásù Tó O sì Ń Kọ́ni

17:2, 3, 17, 22, 23

Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù?

  • A lè fèrò wérò pẹ̀lú àwọn èèyàn tá à ń bá sọ̀rọ̀ látinú Ìwé Mímọ́, ká sì gbé ọ̀rọ̀ wa kalẹ̀ lọ́nà tó máa yé wọn

  • A tún lè lọ wàásù níbi tá a ti máa rí àwọn èèyàn àti nígbà tó ṣeé ṣe ká rí wọn

  • A lè dọ́gbọ́n gbà pẹ̀lú ohun tí onílé gbà gbọ́ ká lè bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ wa látibẹ̀