December 3-9
ÌṢE 9-11
Orin 115 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹni Tó Ń Ṣe Inúnibíni Di Ẹni Tó Ń Fìtara Wàásù”: (10 min.)
Iṣe 9:1, 2—Sọ́ọ̀lù ṣe inúnibíni tó le gan-an sáwọn ọmọlẹ́yìn Jésù (bt 60 ¶1-2)
Iṣe 9:15, 16—Jésù yan Sọ́ọ̀lù láti máa sọ ìhìn rere nípa òun (w16.06 7 ¶4)
Iṣe 9:20-22—Sọ́ọ̀lù di ẹni tó ń fi ìtara wàásù nípa Jésù (bt 64 ¶15)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Iṣe 9:4—Kí nìdí tí Jésù fi bi Sọ́ọ̀lù pé: “Èé ṣe tí ìwọ fi ń ṣe inúnibíni sí mi?” (bt 60-61 ¶5-6)
Iṣe 10:6—Kí nìdí tó fi yani lẹ́nu pé Pétérù ń sùn sọ́dọ̀ ẹni tó jẹ́ oníṣẹ́ awọ? (“Símónì kan, oníṣẹ́ awọ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 10:6, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 9:10-22
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 6
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 16 ¶15-22 àti àpótí Ṣé Ìbẹ́mìílò Ni Lóòótọ́ [Kò pọn dandan kẹ́ ẹ ka àpótí tàbí àfikún]
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 59 àti Àdúrà