Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

December 31, 2018–​January 6, 2019

ÌṢE 19-20

December 31, 2018–​January 6, 2019
  • Orin 103 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ẹ Kíyè Sí Ara Yín àti Gbogbo Agbo”: (10 min.)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 19:9​—Àpẹẹrẹ wo ni Pọ́ọ̀lù fi lélẹ̀ tó bá di pé ká jẹ́ òṣìṣẹ́ kára ká sì tún máa mú ara wa bá ipò àwọn tá à ń wàásù fún mu? (bt 161 ¶11)

    • Iṣe 19:19​—Àpẹẹrẹ wo ni àwọn ará Éfésù fi lélẹ̀ tí àwa náà lè fara wé? (bt 162-163 ¶15)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 19:​1-20

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní káàdì ìkànnì JW.ORG.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Bíbélì àti ìbéèrè fún ìgbà míì.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 15

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 99

  • Ẹ Dá Àwọn Ọ̀dọ́kùnrin Tí Wọ́n Ṣe Tán Láti Ran Ìjọ Lọ́wọ́ Lẹ́kọ̀ọ́: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará ní àwọn ìbéèrè yìí: Ipa pàtàkì wo làwọn alàgbà ń kó nínú ìjọ? (Iṣe 20:28) Kí nìdí tó fi yẹ káwọn alàgbà máa dá àwọn míì lẹ́kọ̀ọ́? Báwo ni àwọn alàgbà ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù nígbà tó dá àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́? Ọwọ́ wo ló yẹ kí àwọn arákùnrin fi mú ìdálẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n ń gbà? (Iṣe 20:35; 1Ti 3:1) Ìdálẹ́kọ̀ọ́ tó gbéṣẹ́ wo ni àwọn alàgbà lè fún wọn? Ojú wo ló yẹ kí àwọn alàgbà fi máa wo àwọn tí wọ́n ń dá lẹ́kọ̀ọ́?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 1 ¶6-13

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 118 àti Àdúrà