Àwọn arábìnrin kan ń fi ọ̀kan lára àwọn fídíò tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ wàásù ní Switzerland

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI December 2019

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí Bíbélì nípa bá a ṣe lè láyọ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Bù Kún Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn Tí Ẹnikẹ́ni Kò Lè Kà

Báwo ni ìwo náà ṣe lè di ọ̀kan lára ogunlọ́gọ̀ èèyàn yìí kó o lè gbádùn ìbùkún Ọlọ́run?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè

Kí ni ìtumọ̀ ìran tí àpọ́sítélì Jòhánù rí nípa àwọn ẹlẹ́rìí méjì náà?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ilẹ̀ ‘Gbé Odò Náà Mì’

Báwo ni Jèhófà ṣe ran àwọn tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n lọ́wọ́ nítorí ìgbàgbọ́ wọn?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Má Ṣe Bẹ̀rù Àwọn Ẹranko Abàmì Náà

Kí la lè ṣe tá ò fi ní máa bẹ̀rù àwọn ẹranko abàmì tó wà nínú ìwé Ìfihàn 13?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ogun Tó Máa Fòpin sí Gbogbo Ogun

Kí nìdí tí Ọlọ́run fi fẹ́ ja ogun yìí, báwo la ṣe lè là á já?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Wò Ó! Mò Ń Sọ Ohun Gbogbo di Tuntun”

Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa sọ ohun gbogbo di tuntun, kí nìyẹn sì túmọ̀ sí fún wa?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Máa Yíwọ́ Pa Dà

Báwo la ṣe lè yíwọ́ pa dà lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù?