Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 13-16

Má Ṣe Bẹ̀rù Àwọn Ẹranko Abàmì Náà

Má Ṣe Bẹ̀rù Àwọn Ẹranko Abàmì Náà

13:1, 2, 11, 15-17

Tá a bá mọ ohun táwọn ẹranko inú Ìfihàn orí 13 dúró fún, ìyẹn ò ní jẹ́ ká máa bẹ̀rù wọn tàbí ká máa gbé wọn gẹ̀gẹ̀ bíi táwọn èèyàn ayé.

Tọ́ka sí ohun tí ẹranko kọ̀ọ̀kan dúró fún

ẸRANKO

Dírágónì náà.​—Ifi 13:1, àlàyé ìsàlẹ̀

Ẹranko tó ní ìwo mẹ́wàá àti orí méje.​—Ifi 13:1, 2

Ẹranko tó ní ìwo méjì bí ọ̀dọ́ àgùntàn.​—Ifi 13:11

Ère ẹranko náà.​—Ifi 13:15

 

 

 

 

OHUN TÓ DÚRÓ FÚN

  • Agbára Ayé Gẹ̀ẹ́sì àti Amẹ́ríkà

  • Ìmùlẹ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè àti Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè tó rọ́pò rẹ̀

  • Sátánì Èṣù

  • Gbogbo ìjọba tó ń ta ko Ọlọ́run