Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

December 2-8

ÌFIHÀN 7-9

December 2-8
  • Orin 63 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jèhófà Bù Kún Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn Tí Ẹnikẹ́ni Kò Lè Kà”: (10 min.)

    • Ifi 7:9​—“Ogunlọ́gọ̀ èèyàn” náà dúró níwájú ìtẹ́ Jèhófà (it-1 997 ¶1)

    • Ifi 7:14​—Ogunlọ́gọ̀ èèyàn náà máa la “ìpọ́njú ńlá” já (it-2 1127 ¶4)

    • Ifi 7:15-17​—Lọ́jọ́ iwájú, ogunlọ́gọ̀ èèyàn náà máa gbádùn ìbùkún lórí ilẹ̀ ayé (it-1 996-997)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ifi 7:1​—Kí ni “áńgẹ́lì mẹ́rin tí wọ́n dúró lórí igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé” àti “atẹ́gùn mẹ́rin” náà ṣàpẹẹrẹ? (re 113 ¶4)

    • Ifi 9:11​—Ta ni “áńgẹ́lì ọ̀gbun àìnísàlẹ̀” náà? (it-1 12)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 7:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 93

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 13 ¶5-9

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 27 àti Àdúrà