Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

December 9-15

ÌFIHÀN 10-12

December 9-15
  • Orin 26 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè”: (10 min.)

    • Ifi 11:3​—‘Àwọn ẹlẹ́rìí méjì’ náà fi ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀fà (1,260) ọjọ́ sọ tẹ́lẹ̀ (w14 11/⁠15 30)

    • Ifi 11:7​—“Ẹranko tó jáde látinú ọ̀gbun àìnísàlẹ̀” pa wọ́n

    • Ifi 11:11​—Ọlọ́run jí ‘àwọn ẹlẹ́rìí méjì’ náà dìde lẹ́yìn “ọjọ́ mẹ́ta àtààbọ̀”

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ifi 10:9, 10​—Báwo ni àkájọ ìwé tí wọ́n fún Jòhánù ṣe “korò,” tó sì tún “dùn”? (it-2 880-881)

    • Ifi 12:1-5​—Báwo làwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe ṣẹ? (it-2 187 ¶7-9)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 10:1-11 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI