Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 10-12

Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè

Wọ́n Pa ‘Àwọn Ẹlẹ́rìí Méjì,’ àmọ́ Wọ́n Pa Dà Wà Láàyè

11:3-11

  • ‘Àwọn ẹlẹ́rìí méjì’: Díẹ̀ lára àwọn ẹni àmì òróró, àwọn yìí ló ń múpò iwájú nígbà tí Ìjọba Ọlọ́run bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso lọ́dún 1914

  • Wọ́n pa wọ́n: Lẹ́yìn tí wọ́n ti wàásù fún ọdún mẹ́ta àtààbọ̀ nínú “aṣọ ọ̀fọ̀,” àwọn alátakò “pa wọ́n” ní ti pé wọ́n jù wọ́n sẹ́wọ̀n, wọ́n sì dáwọ́ iṣẹ́ àwọn ẹlẹ́rìí méjì náà dúró

  • Wọ́n pa dà wà láàyè: Lẹ́yìn tí ọjọ́ mẹ́ta àtààbọ̀ ìṣàpẹẹrẹ náà parí, wọ́n pa dà wà láàyè ní ti pé wọ́n dá wọn sílẹ̀ lẹ́wọ̀n, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í múpò iwájú lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù