December 28, 2020–January 3, 2021
LÉFÍTÍKÙ 16-17
Orin 41 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bí Ọjọ́ Ètùtù Ṣe Kàn Ẹ́”: (10 min.)
Le 16:12—Lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ, àlùfáà àgbà dúró níwájú Jèhófà (w19.11 21 ¶4)
Le 16:13—Àlùfáà àgbà sun tùràrí níwájú Jèhófà (w19.11 21 ¶5)
Le 16:14, 15—Lẹ́yìn náà, àlùfáà àgbà máa ṣètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ àwọn àlùfáà àtàwọn èèyàn tó kù (w19.11 21 ¶6)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Le 16:10—Báwo ni ohun tí wọ́n máa ń fi ewúrẹ́ Ásásélì ṣe ṣe jọra pẹ̀lú ẹbọ tí Jésù rú? (it-1 226 ¶3)
Le 17:10, 11—Kí ló mú ká pinnu pé a ò ní gbẹ̀jẹ̀ sára? (w14 11/15 10 ¶10)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 16:1-17(th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún ẹni náà ní ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 1 ¶1-2 (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ṣé Wàá Fẹ́ Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Àwọn Míṣọ́nnárì Ń Ṣíṣẹ Kára Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) rr orí 2 ¶19-27
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 50 àti Àdúrà