Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | NEHEMÁYÀ 1-4

Nehemáyà Fẹ́ràn Ìjọsìn Tòótọ́

Nehemáyà Fẹ́ràn Ìjọsìn Tòótọ́

455 B.C.E.

  1. Nísàn (Mar. sí Apr.)

    2:4-6 Nehemáyà gba àṣẹ láti tún Jerúsálẹ́mù tí wọ́n ti ń ṣe ìjọsìn tòótọ́ ní àkókò rẹ̀ kọ́

  2. Ííyà

  3. Sífánì

  4. Támúsì (June sí July)

    2:11-15 Nehemáyà dé Jerúsálẹ́mù nírú àkókò yìí, ó sì ṣàyẹ̀wò ògiri ìlú náà

  5. Ábì (July sí Aug.)

    3:1; 4:7-9 Wọ́n bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìkọ́lé náà láìka àtakò sí

  6. Élúlì (Aug. sí Sept.)

    6:15 Wọ́n parí mímọ ògiri náà lẹ́yìn ọjọ́ méjìléláàádọ́ta [52]

  7. Tíṣírì