February 13-19
Aísáyà 52-57
Orin 148 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kristi Jìyà fún Wa”: (10 min.)
Ais 53:3-5
—Wọ́n tẹ́ńbẹ́lú rẹ̀, wọ́n sì tẹ̀ ẹ́ rẹ́ nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa (w09 1/15 26 ¶3-5) Ais 53:7, 8
—Ó fẹ̀mí ara rẹ̀ rúbọ fún wa tinútinú (w09 1/15 27 ¶10) Ais 53:11, 12
—Àwa náà lè ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Ọlọ́run torí pé Jésù jẹ́ olóòótọ́ títí dójú ikú (w09 1/15 28 ¶13)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ais 54:1
—Ta ni “àgàn tí kò bímọ” tí àsọtẹ́lẹ̀ yìí tọ́ka sí, àwọn wo sì ni “àwọn ọmọ” rẹ̀? (w06 3/15 11 ¶2) Ais 57:15
—Kí ni Jèhófà ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé òun ń “gbé” pẹ̀lú “àwọn tí a tẹ̀ rẹ́” àti “àwọn ẹni rírẹlẹ̀”? (w05 10/15 26 ¶3) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 57:1-11
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll 6
—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll 7
—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 14-15 ¶16-17
—Tó bá ṣeé ṣe, ẹ jẹ́ kí bàbá kan bá ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin rẹ̀ kékeré ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 110
“Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ní Ìgbàgbọ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Nínú Ẹlẹ́dàá”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò yìí Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ
—Ọlọ́run Wà Lóòótọ́. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 8 ¶8-13 àti “Àtẹ Àwọn Ìwé Tí Wọ́n Ń Tẹ̀ Jáde Jù Láyé”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 107 àti Àdúrà