February 27–March 5
Aísáyà 63-66
Orin 19 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ọ̀run Tuntun àti Ayé Tuntun Máa Mú Ká Láyọ̀ Tó Kọ Yọyọ”: (10 min.)
Ais 65:17
—“Àwọn ohun àtijọ́ ni a kì yóò sì mú wá sí ìrántí” (ip-2 383 ¶23) Ais 65:18, 19
—A máa láyọ̀ tó kọ yọyọ (ip-2 384 ¶25) Ais 65:21-23
—A máa ní ìtẹ́lọ́rùn, ọkàn wa sì máa balẹ̀ (w12 9/15 9 ¶4-5)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ais 63:5
—Báwo ni ìhónú Ọlọ́run ṣe ń tì í lẹ́yìn? (w07 1/15 11 ¶6) Ais 64:8
—Báwo ni Jèhófà ṣe ń lo àṣẹ tó ní gẹ́gẹ́ bí amọ̀kòkò wa? (w13 6/15 25 ¶3-) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 63:1-10
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ef 5:33
—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Ti 5:8; Tit 2:4, 5
—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 66:23; w06 11/1 30-31 ¶14-17
—Àkòrí: Pípàdé Pọ̀ —Ohun Kan Tí Kò Ní Yí Padà Nínú Ìjọsìn Wa
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 129
“Jẹ́ Kí Ìrètí Tó O Ní Máa Fún Ẹ Láyọ̀” (Ais 65:17, 18; Ro 12:12): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ẹ Máa Yọ̀ Nínú Ìrètí.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 9 ¶1-9, àtẹ “Ìbísí Kárí Ayé”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 95 àti Àdúrà