Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ṣé Bíbélì ṣì wúlò lóde òní?

Bíbélì: 2Ti 3:⁠16

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ṣé Bíbélì àti sáyẹ́ǹsì bára mu?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ṣé Bíbélì àti sáyẹ́ǹsì bára mu?

Bíbélì: Jóòbù 26:7

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ǹjẹ́ àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì ṣì wúlò?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Ǹjẹ́ àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì ṣì wúlò?

Bíbélì: Owe 14:30

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ṣé àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì nípa ọjọ́ iwájú péye?