Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

February 26–​March 4

MÁTÍÙ 18-19

February 26–​March 4
  • Orin 121 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Yẹra Pátápátá fún Ohun Tó Lè Mú Ìwọ Àtàwọn Míì Kọsẹ̀”: (10 min.)

    • Mt 18:​6, 7​—A kò gbọ́dọ̀ mú àwọn míì kọsẹ̀ (“ọlọ tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ máa ń yí,” “ohun ìkọ̀sẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ pẹ̀lú fídíò àti àwòrán “Ọlọ,” “Ọmọ Ọlọ àti Ìya Ọlọ” lórí Mt 18:6, 7, nwtsty)

    • Mt 18:​8, 9​—A gbọ́dọ̀ yẹra fún ohunkóhun tó lè mú wa kọsẹ̀ (“Gẹ̀hẹ́nà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 18:9, nwtsty àti àlàyé àwọn ọ̀rọ̀ Bíbélì)

    • Mt 18:10​—Jèhófà máa ń mọ̀ tá a bá ti mú ẹnì kan kọsẹ̀ (“wo ojú Baba mi” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 18:10 nwtsty; w10 11/1 16)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mt 18:​21, 22​—Ìgbà mélòó ló yẹ ká máa dárí ji àwọn arákùnrin wa? (“Ìgbà 77” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mt 18:22, nwtsty)

    • Mt 19:7​—Kí ni “ìwé ẹ̀rí ìlélọ” wà fún? (“ìwé ẹ̀rí ìlélọ” àlàyé ọ̀rọ̀ pẹ̀lú fídíò àti àwòrán “Ìwé Ìkọ̀sílẹ̀” lórí Mt 19:7, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mt 18:​18-35

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o fẹ́ kà, kí o sì fi ọ̀kan lára àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ wa lọni.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 25-26 ¶18-20​—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 90

  • Má Ṣe Jẹ́ Okùnfà Ìkọ̀sẹ̀ (2Kọ 6:3): (9 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.

  • A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Pe Àwọn Èèyàn sí Ìrántí Ikú Kristi ní March 3: (6 min.) Àsọyé tó dá lórí Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni ti February 2016, ojú ìwé 8. Pín ẹ̀dà ìwé ìkésíni fún ẹnì kọ̀ọ̀kan tó wà nípàdé, kó o sì sọ àwọn ohun tó wà nínú rẹ̀. Pe àfíyèsí àwọn ará sí àkànṣe àsọyé náà “Ta Ni Jésù Kristi Jẹ́ Gan-an?” tó máa wáyé ní ọ̀sẹ̀ March 19, 2018. Èyí máa jẹ́ kí ara àwọn èèyàn wà lọ́nà fún Ìrántí Ikú Kristi. Sọ ètò tí ìjọ ti ṣe láti kárí ìpínlẹ̀ ìwàásù yín.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 4, Àpótí “Fetí Sí Ìmọ̀ràn Kí O Sì Gba Ìbáwí” àti “Ẹ Jẹ́ Onígbọràn Sí Àwọn Tí Ń Mú Ipò Iwájú

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 133 àti Àdúrà