Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Àǹfààní Tá A Lè Rí Nínú Ìtumọ̀ Àwọn Àpèjúwe Ìjọba Ọlọ́run

Àǹfààní Tá A Lè Rí Nínú Ìtumọ̀ Àwọn Àpèjúwe Ìjọba Ọlọ́run

Jésù lo àwọn àpèjúwe tó rọrùn láti kọ́ àwọn èèyàn ní àwọn ẹ̀kọ́ tẹ̀mí tó jinlẹ̀. Àmọ́ àwọn onírẹ̀lẹ̀ nìkan ni wọ́n béèrè ìtumọ̀ wọn tí wọ́n sì fi ẹ̀kọ́ náà sílò. (Mt 13:​10-15) Wo àlàyé lórí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn àpèjúwe Ìjọba náà, lẹ́yìn náà kó o dáhùn àwọn ìbéèrè tó tẹ̀ lé e yìí: Báwo ni mo ṣe lè jàǹfààní nínú àpèjúwe yìí? Báwo ni mo ṣe lè lò ó ní ìgbésí ayé mi?

ÌJỌBA Ọ̀RUN DÀ BÍ . . .

  • “hóró músítádì kan.”​—Mt 13:​31, 32; w14 12/15 8 ¶9.

  • “ìyẹ̀fun.”​—Mt 13:33; w14 12/15 9-10 ¶14-15.

  • “ìṣúra” àti “olówò arìnrìn-àjò kan.”​—Mt 13:44-46; w14 12/15 10 ¶18.