ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI February 2019
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Ìjíròrò tó dá lórí ìwúlò Bíbélì lóde òní.
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Máa Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ
Ẹ̀rí ọkàn wa máa ṣiṣẹ́ dáadáa tá a bá fi àwọn ìlànà Bíbélì kọ́ ọ.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ṣé O Máa Ń Rí Àwọn Ànímọ́ Ọlọ́run Tí A Kò Lè Rí?
Àwọn nǹkan tí Jèhófà dá fi hàn pé alágbára ni, ó nífẹ̀ẹ́ wa, ó gbọ́n, onídàájọ́ òdodo ni, ọ̀làwọ́ sì ni.
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Tirẹ̀ fún Wa”
Bàwo la ṣe lè fi hàn pé a mọrírì ẹ̀bùn ìràpadà tí Jèhófà fún wa?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ṣé Ò Ń Fojú Sọ́nà Pẹ̀lú Ìháragàgà?
Báwo lo ṣe lè fi hàn pé o wà ní ìmúratán fún “ìṣípayá àwọn ọmọ Ọlọ́run”?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Máa Fi Ìháragàgà Dúró Dè É Pẹ̀lú Ìfaradà
Kí ló máa ràn wá lọ́wọ́ láti máa fi ìháragàgà dúró, tí ìṣòro èyíkéyìí bá tiẹ̀ ń bá wa fínra?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Fòpin Sí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Tí Kò Méso Jáde
Tí ẹnì kan tá à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ò bá tẹ̀ síwájú nípa tẹ̀mí lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́, kí la lè ṣe?