February 25–March 3
RÓÒMÙ 9-11
Orin 25 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Àpèjúwe Igi Ólífì”: (10 min.)
Ro 11:16—Igi ólífì tá a gbìn yìí ṣàpẹẹrẹ bí májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá Ábúráhámù dá ṣe ní ìmúṣẹ (w11 5/15 23 ¶13)
Ro 11:17, 20, 21—Àwọn ẹni àmì òróró tá a lọ́ mọ́ igi olófì yẹn gbọ́dọ̀ máa lo ìgbàgbọ́ (w11 5/15 24 ¶15)
Ro 11:25, 26—Gbogbo àwọn tó para pọ̀ di Ísírẹ́lì tẹ̀mí máa rí ìgbàlà (w11 5/15 25 ¶19)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ro 9:21-23—Kí nìdí tó fi yẹ ká gba Jèhófà láyè láti mọ wá? (w13 6/15 25 ¶5)
Ro 10:2—Kí nìdí tó fi yẹ ká rí i dájú pé a gbé ìjọsìn wa ka ìmọ̀ tó péye? (it-1 1260 ¶2)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 10:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Fi ìpadàbẹ̀wò kejì bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ, lẹ́yìn náà fi ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú onílé. (th ẹ̀kọ́ 9)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Fòpin Sí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Tí Kò Méso Jáde”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 3 ¶7-12
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 36 àti Àdúrà