Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 1-3

Máa Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ

Máa Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ

2:14, 15

Ẹ̀rí ọkàn wa máa ṣiṣẹ́ dáadáa tá a bá

  1. fi àwọn ìlànà Bíbélì kọ́ ọ

  2. tẹ́tí sí i nígbà tó bá rán wa létí àwọn ìlànà yẹn

  3. gbàdúrà pé kí ẹ̀mí mímọ́ ràn wá lọ́wọ́ láti máa ṣe ohun tó tọ́.​—Ro 9:1