Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 4-5

Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Ìwàásù Jésù Lórí Òkè

Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Ìwàásù Jésù Lórí Òkè

5:3

Ṣé àwọn àìní rẹ nípa tẹ̀mí ń jẹ ọ́ lọ́kàn?

Gbólóhùn náà “àwọn tí àìní wọn nípa ti ẹ̀mí ń jẹ lọ́kàn” túmọ̀ sí àwọn tó ń bẹ̀bẹ̀ fún ẹ̀mí. (Mt 5:3.) A lè fi hàn pé ó wù wá gidigidi pé kí Ọlọ́run ràn wá lọ́wọ́ nípa tẹ̀mí, tá a bá ń . . .

  • ka Bíbélì lójoojúmọ́

  • múra àwọn ìpàdé ìjọ sílẹ̀, ká sì máa lọ sípàdé déédéé

  • wá àyè láti ka àwọn ìtẹ̀jáde wa tó fi mọ́ àwọn nǹkan tó wà lórí ìkànnì wa

  • wo ètò òṣooṣù Tẹlifíṣọ̀n JW

Báwo ni mo ṣe lè túbọ̀ ṣètò ara mi kí n lè máa gbádùn oúnjẹ tẹ̀mí?