January 18-24
LÉFÍTÍKÙ 22-23
Orin 86 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Le 22:21, 22—Kí nìdí tó fi yẹ ká fi gbogbo ọkàn wa jẹ́ olóòótọ́ àti adúróṣinṣin sí Jèhófà? (w19.02 3 ¶3)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Le 23:9-25 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ìtẹ̀jáde tó dáhùn ìbéèrè kan tó béèrè. (th ẹ̀kọ́ 13)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 9)
Àsọyé: (5 min.) w07 7/15 26—Àkòrí: Ta Ló Máa Ń Kórè Àkọ́so Ọkà Bálì Tí Wọ́n Máa Ń Gbé Wá Sínú Ibi Mímọ́? (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“À Ń Fìfẹ́ Hàn Láwọn Àpéjọ Tá À Ń Ṣe Lọ́dọọdún”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àpéjọ Àgbáyé “Ìfẹ́ Kì Í Yẹ̀ Láé”!
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 3 ¶11-20
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 9 àti Àdúrà