February 8-14
NỌ́ŃBÀ 1-2
Orin 123 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Nọ 1:2, 3—Kí nìdí tí Jèhófà fi ní káwọn ọmọ Ísírẹ́lì forúkọ sílẹ̀? (it-2 764)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 1:1-19 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ ohun tó máa bá ipò onílé mu, kó o sì ka ẹsẹ Bíbélì tó máa wọ̀ ọ́ lọ́kàn. (th ẹ̀kọ́ 12)
Àsọyé: (5 min.) w08 7/1 21—Àkòrí: Kí Nìdí Tí Bíbélì Fi Sábà Máa Ń Sọ̀rọ̀ Nípa Ẹ̀yà Ísírẹ́lì Méjìlá, Nígbà Tó Jẹ́ Pé Ẹ̀yà Mẹ́tàlá Ni Wọ́n? (th ẹ̀kọ́ 7)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jèhófà Fẹ́ Ká Wàásù fún Gbogbo Èèyàn”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Máa Wàásù fún Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Míì. Mẹ́nu ba àwọn nǹkan tó wà lórí ètò ìṣiṣẹ́ JW Language®.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 4 ¶10-17
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 1 àti Àdúrà