ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nọ́ńbà.]
Wọ́n pín àgọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí ẹ̀yà mẹ́ta-mẹ́ta (Nọ 1:52, 53; w94 12/1 9 ¶4)
Ó ṣeé ṣe kí gbogbo wọn lápapọ̀ tó mílíọ̀nù mẹ́ta tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ (Nọ 2:32, 33; it-1 397 ¶4)
Jèhófà fẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa wà létòlétò bí wọ́n ṣe ń jọ́sìn òun, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀. Ohun kan náà là ń ṣe lónìí.—1Kọ 14:33, 40.
BI ARA RẸ PÉ, ‘Kí ni mo lè ṣe láti fi hàn pé mò ń fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ètò Ọlọ́run?’