January 11-17
LÉFÍTÍKÙ 20-21
Orin 80 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Le 21:5—Kí nìdí tí Òfin Ọlọ́run fi sọ pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò gbọ́dọ̀ dá ọgbẹ́ sí ara wọn? (it-1 563)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Le 20:1-13 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Àdúrà—1Jo 5:14. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ìwé Ìròyìn Ayọ̀, kó o sì fi ẹ̀kọ́ 12 bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 19)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ṣe Ohun Tá Jẹ́ Kí Ìgbéyàwó Rẹ Lágbára Sí I”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà A Gbọ́dọ̀ ‘Fi Ìfaradà Sáré’—Máa Tẹ̀ Lé Òfin Eré Sísá.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr apá 1, orí 3 ¶1-10, fídíò ohun tó wà ní orí 3 àti àpótí 3A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 94 àti Àdúrà