Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Sọ́ọ̀lù Nírẹ̀lẹ̀, Ó Sì Mọ̀wọ̀n Ara Ẹ̀ Níbẹ̀rẹ̀

Sọ́ọ̀lù Nírẹ̀lẹ̀, Ó Sì Mọ̀wọ̀n Ara Ẹ̀ Níbẹ̀rẹ̀

Sọ́ọ̀lù mọ̀wọ̀n ara ẹ̀, kò sì kọ́kọ́ gbà nígbà tí wọ́n fẹ́ fi jọba (1Sa 9:21; 10:20-22; w20.08 10 ¶11)

Sọ́ọ̀lù ò bínú nígbà táwọn kan pẹ̀gàn ẹ̀ (1Sa 10:27; 11:12, 13; w14 3/15 9 ¶8)

Sọ́ọ̀lù jẹ́ kí ẹ̀mí Jèhófà darí òun (1Sa 11:5-7; w95 12/15 10 ¶1)

Tá a bá nírẹ̀lẹ̀, a máa gbà pé ẹ̀bùn látọ̀dọ̀ Jèhófà ni àǹfààní iṣẹ́ ìsìn tàbí ẹ̀bùn àbínibí èyíkéyìí tá a ní. (Ro 12:3, 16; 1Kọ 4:7) Bákan náà, tá a bá lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀, àá jẹ́ kí Jèhófà máa darí wa.