ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà
Léraléra làwọn ọmọ Ísírẹ́lì bẹ Jèhófà pé kó tọ́ àwọn sọ́nà (Ond 20:17, 18, 23; w11 9/15 32 ¶2)
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbára lé Jèhófà pátápátá kó lè ràn wọ́n lọ́wọ́ láti mú ẹ̀gàn tí wọ́n kó bá orúkọ rẹ̀ kúrò (Ond 20:26-28)
A ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kó sú wa láti máa wá ìtọ́sọ́nà Jèhófà ká sì gbára lé e pátápátá (Ond 20:35; Lk 11:9; w11 9/15 32 ¶4)
BI ARA Ẹ PÉ: ‘Ṣé ọ̀dọ̀ Jèhófà ni mo máa ń yíjú sí lẹsẹ̀kẹsẹ̀ tí ìṣòro bá yọjú? Ṣé mo máa ń bẹ̀ ẹ́ léraléra láti fún mi ní ọgbọ́n, kó sì tọ́ mi sọ́nà?’