January 24-30
RÚÙTÙ 1-2
Orin 108 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn Míì”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Rut 1:20, 21—Kí nìdí tí Náómì fi sọ pé Jèhófà ló mú káyé òun korò? (w05 3/1 27 ¶2)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Rut 1:1-17 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)
Àsọyé: (5 min.) ia 43-44 ¶5-9—Àkòrí: Àwọn Wo La Lè Kà sí Ìdílé? (th ẹ̀kọ́ 20)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jẹ́ Kó Dá Ẹ Lójú Pé Ìfẹ́ Tí Jèhófà Ní sí Ẹ Kò Ní Yẹ̀ Láé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìròyìn Iṣẹ́ Ìgbìmọ̀ Olùṣekòkáárí 2019.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 19 ¶7-15
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 97 àti Àdúrà