January 31–February 6
RÚÙTÙ 3-4
Orin 39 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bó O Ṣe Lè Ṣe Orúkọ Rere fún Ara Ẹ”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Ìyebíye Míì: (10 min.)
Rut 4:6—Ọ̀nà wo ni olùtúnrà fi lè “run” ogún rẹ̀ tó bá ṣe ìtúnrà? (w05 3/1 29 ¶4)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Rut 4:7-22 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Wá Sípàdé”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Wá Sípàdé.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 03 kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 19 ¶16-21 àti àpótí 19B
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 144 àti Àdúrà