Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Nígbà Àkọ́kọ́ *

Ìbéèrè: Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run ń bójú tó wa lẹ́nì kọ̀ọ̀kan?

Bíbélì: Mt 10:29-31

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ láti fara da àwọn ìṣòro tá à ń kojú lónìí?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

Ìpadàbẹ̀wò *

Ìbéèrè: Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ láti fara da àwọn ìṣòro tá à ń kojú lónìí?

Bíbélì: Jer 29:11

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Bíbélì ṣe ń tọ́ wa sọ́nà?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

^ ìpínrọ̀ 3 ^ ìpínrọ̀ 9 O lè lo ìbéèrè míì tó bá ìpínlẹ̀ ìwàásù yín mu.