Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Nígbà Àkọ́kọ́

Ìbéèrè: Ṣé Ọlọ́run tiẹ̀ máa ń gbọ́ àdúrà?

Bíbélì: Sm 65:2

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn nǹkan wo la lè bá Ọlọ́run sọ nínú àdúrà?

Ìpadàbẹ̀wò

Ìbéèrè: Àwọn nǹkan wo la lè bá Ọlọ́run sọ nínú àdúrà?

Bíbélì: 1Jo 5:14

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń dáhùn àdúrà wa?