ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
A Máa Ṣàṣeyọrí Tá A Bá Ń Tẹ̀ Lé Ìlànà Jèhófà
Dáfídì fẹ́ gbé àpótí májẹ̀mú pa dà sí Jerúsálẹ́mù (1Kr 13:3)
Kò ṣàṣeyọrí torí pé kò tẹ̀ lé ìlànà tó wà fún gbígbé àpótí náà (1Kr 15:13; w03 5/1 10-11)
Dáfídì ṣàṣeyọrí nígbà tó wà ìtọ́sọ́nà Jèhófà (1Kr 15:2; 16:11; w03 5/1 11 ¶13)
Jèhófà mọyì àwọn ohun rere tí à ń ṣe. Àmọ́, kí Jèhófà tó lè tẹ́wọ́ gba àwọn ohun tá à ń ṣe, a gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ìlànà rẹ̀. —Di 30:16.