Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Dáfídì ṣètò àwọn òṣìṣẹ́ àtàwọn ohun èlò tí Sólómọ́nì máa fi kọ́ tẹ́ńpìlì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí

Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí

Ó dá Dáfídì lójú pé Jèhófà máa ran Sólómọ́nì lọ́wọ́ láti kọ́ tẹ́ńpìlì náà parí (1Kr 22:5; w17.01 29 ¶8)

Dáfídì gba Sólómọ́nì níyànjú pé kó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kó sì máa báṣẹ́ lọ (1Kr 22:11-13)

Dáfídì ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe láti pèsè ohun tí Sólómọ́nì nílò fún iṣẹ́ náà (1Kr 22:14-16; w17.01 29 ¶7; wo àwòrán iwájú ìwé)

BI ARA Ẹ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè ran àwọn ọ̀dọ́ tó wà nínú ìjọ mi lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣàṣeyọrí, kí wọ́n sì láyọ̀ bí wọ́n ṣe ń sin Jèhófà?’—w18.03 11-12 ¶14-15.