Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

February 6-12

1 KÍRÓNÍKÀ 10-12

February 6-12
  • Orin 94 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jẹ́ Kó Máa Wù Ẹ́ Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 1Kr 12:33—Àpẹẹrẹ rere wo ni ọ̀kẹ́ méjì ààbọ̀ (50,000) àwọn ọkùnrin Sébúlúnì fi lélẹ̀? (it-1 1058 ¶5-6)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Kr 11:26-47 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI