ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Òótọ́ Làwọn Ìtàn Bíbélì, Kì Í Ṣe Àròsọ
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Kíróníkà Kìíní.]
Èèyàn bí tiwa ni Ádámù (1Kr 1:1; w09 9/1 14 ¶1)
Èèyàn bí tiwa náà ni Nóà (1Kr 1:4; w08 6/1 3 ¶4)
Tá a bá gbà pé ẹni gidi ni àwọn tá a sọ̀rọ̀ wọn nínú Bíbélì, á jẹ́ kó rọrùn fún wa láti tẹ̀ lé àpẹẹrẹ wọn.—1Kọ 15:22; w09 9/1 14-15.