ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Kí Ni Àdúrà Mi Ń Sọ Nípa Irú Ẹni Tí Mo Jẹ́?
Ẹni iyì ni Jábésì (1Kr 4:9)
Àdúrà Jábésì fi hàn pé ó mọrírì ìjọsìn mímọ́ (1Kr 4:10a; w10 10/1 23 ¶3-7)
Jèhófà dáhùn àdúrà Jábésì (1Kr 4:10b)
BI ARA RẸ PÉ, ‘Kí ni àdúrà mi ń sọ nípa irú ẹni tí mo jẹ́?’—Mt 6:9, 10.