January 30–February 5
1 KÍRÓNÍKÀ 7-9
Orin 84 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Tó Le Gan-an”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Kr 9:33—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe jẹ́ ká mọ̀ pé orin kíkọ ṣe pàtàkì nínú ìjọsìn wa sí Jèhófà? (w10 12/15 21 ¶6)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Kr 7:1-13 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 16)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 20)
Àsọyé: (5 min.) w21.06 3-4 ¶3-8—Àkòrí: Ran Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Lọ́wọ́ Kó Lè Máa Fi Ohun Tó Ń Kọ́ Sílò. (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jèhófà Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Lákòókò Ìṣòro”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 36
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 31 àti Àdúrà