February 5-11
SÁÀMÙ 1-4
Orin 150 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Fara Mọ́ Ìjọba Ọlọ́run
(10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù.]
Àwọn aláṣẹ ayé ti sọ ara wọn di ọ̀tá Ìjọba Ọlọ́run (Sm 2:2; w21.09 15 ¶8)
Jèhófà ń fún gbogbo èèyàn láǹfààní láti pinnu bóyá wọ́n máa fara mọ́ Ìjọba rẹ̀ (Sm 2:10-12)
BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mo ti pinnu pé mi ò ní dá sí ọ̀rọ̀ òṣèlú lọ́nàkọnà, kódà tíyẹn bá máa mú kí nǹkan nira fún mi?’—w16.04 24 ¶11.
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Sm 1:4—Báwo làwọn èèyàn burúkú ṣe dà bí “ìyàngbò tí afẹ́fẹ́ ń gbá lọ”? (it-1 425)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Sm 3:1–4:8 (th ẹ̀kọ́ 12)
4. Máa Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Ẹ Wẹ́rẹ́—Ohun Tí Fílípì Ṣe
(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 1-2.
5. Máa Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Ẹ Wẹ́rẹ́—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Fílípì
(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 3-5 àti apá “Tún Wo.”
Orin 32
6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 5 ¶9-15, àpótí tó wà lójú ìwé 41