Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

January 13-19

SÁÀMÙ 135-137

January 13-19

Orin 2 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. “Olúwa Wa Ju Gbogbo Ọlọ́run Yòókù Lọ”

(10 min.)

Jèhófà ti fi hàn pé òun láṣẹ lórí gbogbo ohun tóun dá (Sm 135:5, 6; it-2 661 ¶4-5)

Ó máa ń gbèjà àwọn èèyàn rẹ̀ (Ẹk 14:29-31; Sm 135:14)

Ó máa ń ràn wá lọ́wọ́ tá a bá rẹ̀wẹ̀sì (Sm 136:23; w21.11 6 ¶16)

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 135:1, 5—Kí nìdí tí Bíbélì fi sábà máa ń lo ọ̀rọ̀ náà “Jáà”? (it-1 1248)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Gba nọ́ńbà ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sọ́rọ̀ ẹ. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 4)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ DÉ ILÉ. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 4)

6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́

(5 min.) Àṣefihàn. ijwfq àpilẹ̀kọ 7—Àkòrí: Ṣé Kristẹni Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà? (th ẹ̀kọ́ 12)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 10

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 90 àti Àdúrà