July 18 sí 24
SÁÀMÙ 74-78
Orin 110 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Rántí Àwọn Iṣẹ́ Jèhófà”: (10 min.)
Sm 74:16; 77:6, 11, 12—Máa ṣàṣàrò lórí àwọn iṣẹ́ Jèhófà (w15 8/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 3 àti 4; w04 3/1 ojú ìwé 19 àti 20; w03 7/1 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 6 àti 7)
Sm 75:4-7—Lára àwọn iṣẹ́ Jèhófà ni bó ṣe yan àwọn ọkùnrin onírẹ̀lẹ̀ láti máa bójú tó ìjọ rẹ̀ (w06 7/15 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 2; it-1 ojú ìwé 1160 ìpínrọ̀ 7)
Sm 78:11-17—Máa rántí bí Jèhófà ṣe gbèjà àwọn èèyàn rẹ̀ nígbà àtijọ́ (w04 4/1 ojú ìwé 21 àti 22)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Sm 78:2—Báwo ni Mèsáyà ṣe mú àsọtẹ́lẹ̀ tó wà nínú ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí ṣẹ? (w11 8/15 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 14)
Sm 78:40, 41—Kí ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí jẹ́ ká mọ̀ nípa bí ìwà àti ìṣe wa ṣe máa ń rí lára Jèhófà? (w12 11/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 5; w11 7/1 ojú ìwé 10)
Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 78:1-21
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.4 ojú ìwé 16—Sọ bí a ṣe ń fi ọrẹ ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ wa.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.4 ojú ìwé 16
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 5 ìpínrọ̀ 6 àti 7
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 15
Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (10 min.)
“Jèhófà . . . Ni Ó Dá Ohun Gbogbo”: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò yìí tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo (Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ.) Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n ní ìbéèrè nípa fídíò náà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 20 ìpínrọ̀ 1 sí 13
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 73 àti Àdúrà