July 4 sí 10
SÁÀMÙ 60-68
Orin 104 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Yin Jèhófà, Olùgbọ́ Àdúrà”: (10 min.)
Sm 61:1, 8
—Tó o bá ṣèlérí fún Jèhófà, máa bẹ̀ ẹ́ pé kó ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè mú ìlérí rẹ ṣẹ (w99 9/15 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 1 sí 4) Sm 62:8
—Tó o bá sọ gbogbo ohun tó wà lọ́kàn rẹ fún Jèhófà, ìyẹn á fi hàn pé o gbẹ́kẹ̀ lé e (w15 4/15 ojú ìwé 25 àti 26 ìpínrọ̀ 6 sí 9) Sm 65:1, 2
—Jèhófà ni Olùgbọ́ àdúrà gbogbo àwọn tó lọ́kàn rere (w15 4/15 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 13 àti 14; w10 4/15 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 10; it-2 ojú ìwé 668 ìpínrọ̀ 2)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 63:1–64:10
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kó o sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kọ àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 81
“Jẹ́ Kí Ohun Díẹ̀ Tẹ́ Ọ Lọ́rùn Kó O Lè Túbọ̀ Máa Yin Ọlọ́run”: (15 min.) Ẹ kọ́kọ́ jíròrò àpilẹ̀kọ náà. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní A Jẹ́ Kóhun Díẹ̀ Tẹ́ Wa Lọ́rùn, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ ní ṣókí. Fídíò yìí wà lórí ètò Tẹlifíṣọ̀n JW (Lọ sí WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > ÌDÍLÉ.) Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n wo àwọn ọ̀nà tí wọ́n lè gbà jẹ́ kí ohun díẹ̀ tẹ́ wọn lọ́rùn kí wọ́n lè túbọ̀ máa sin Jèhófà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 19 ìpínrọ̀ 1 sí 16
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 88 àti Àdúrà