July 9-15
Lúùkù 8-9
Orin 13 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kí Ló Túmọ̀ Sí Láti Di Ọmọlẹ́yìn?”: (10 min.)
Lk 9:57, 58—Àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù gbọ́dọ̀ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà (it-2 494)
Lk 9:59, 60—Àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù máa ń fi Ìjọba Ọlọ́run sípò àkọ́kọ́ láyé wọn (“sìnkú baba mi,” “Jẹ́ kí àwọn òkú máa sin òkú wọn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 9:59, 60, nwtsty)
Lk 9:61, 62—Àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù kò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí àwọn nǹkan ayé pín ọkàn wọn níyà (“Títúlẹ̀,” àwòrán àti fídíò lórí Lk 9:61, 62, nwtsty; w12 4/15 15-16 ¶11-13)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Lk 8:3—Báwo làwọn Kristẹni yìí ṣe “ṣèránṣẹ́” fún Jésù àti àwọn àpọ́sítélì? (“ṣèránṣẹ́ fún wọn” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 9:8:3, nwtsty)
Lk 9:49, 50—Kí nìdí tí Jésù kò fi ṣèdíwọ́ fún ọkùnrin kan tó ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ọkùnrin náà kì í tẹ̀ lé Jésù? (w08 3/15 31 ¶2)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 8:1-15
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w12 3/15 27-28 ¶11-15—Àkòrí: Ṣé Ó Yẹ Ká Máa Kábàámọ̀ Àwọn Nǹkan Tá A Yááfì Nítorí Ìjọba Ọlọ́run?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 10 ¶1-8
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 110 àti Àdúrà