ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Gbogbo Ìbùkún Yìí Máa . . . Bá Ọ”
Àwọn tó ṣègbọràn sí Jèhófà rí ọ̀pọ̀ ìbùkún (Di 28:1, 3-6; w10 12/15 19 ¶18)
Ìbùkún tó pọ̀ yanturu ni Jèhófà máa fún àwọn tó bá ń ṣègbọràn sí i (Di 28:2; w01 9/15 10 ¶2)
Jèhófà fẹ́ ká máa “fi ìdùnnú àti ayọ̀ tó wá látọkàn” ṣègbọràn sí òun (Di 28:45-47; w10 9/15 8 ¶4)
Àwọn tó ń ṣègbọràn sí Jèhófà ń rí ọ̀pọ̀ ìbùkún báyìí, Jèhófà tún ṣèlérí pé wọ́n máa rí ìbùkún tó pọ̀ gan-an lọ́jọ́ ìwájú.