Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I

Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I

Tí wọ́n bá rí ẹranko tó wà nínú wàhálà, wọn ò gbọ́dọ̀ pa á tì (Di 22:4; it-1 375-376)

Wọn ò gbọ́dọ̀ hùwà ìkà sí ẹyẹ tó lọ́mọ (Di 22:6, 7; it-1 621 ¶1)

Wọn ò gbọ́dọ̀ fi ẹranko tó yàtọ̀ síra túlẹ̀ pa pọ̀ (Di 22:10; w03 10/15 32 ¶1-2)

Jèhófà fẹ́ ká máa bójú tó àwọn ẹranko, torí wọ́n ṣe pàtàkì sí i. A ò gbọ́dọ̀ hùwà ìkà sí àwọn ẹranko tàbí ká kàn máa pa wọ́n ṣeré.​—Owe 12:10.