August 23-29
DIUTARÓNÓMÌ 29-30
Orin 3 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kò Nira Jù Láti Sin Jèhófà”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Di 29:4—Kí la rí kọ́ lára ohun tó ṣẹlẹ̀ sáwọn ọmọ Ísírẹ́lì? (it-1 665 ¶3)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 29:1-18 (th ẹ̀kọ́ 2)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ, kó o sì fún onílé ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lv 196-197 ¶3-5 (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Kò Nira Jù Láti Jẹ́ Onígboyà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Tó Nígboyà, Kì Í Ṣe Àwọn Ojo!
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 12 ¶15-21
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 90 àti Àdúrà