Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní

Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń ran àwọn aláìní lọ́wọ́ àtàwọn tí kò ní ogún kankan (Di 14:28, 29; it-2 1110 ¶3)

Lọ́dún Sábáàtì, ọmọ Ísírẹ́lì tó bá jẹ gbèsè máa rí “ìtúsílẹ̀” gbà (Di 15:1-3; it-2 833)

Tọ́mọ Ísírẹ́lì kan bá ta ara ẹ̀ sóko ẹrú, ọ̀gá ẹ̀ gbọ́dọ̀ tú u sílẹ̀ lọ́dún keje, á sì tún fún un lẹ́bùn (Di 15:12-14; it-2 978 ¶6)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Kí ni mo lè ṣe láti fi hàn pé mo nífẹ̀ẹ́ àwọn ará tó jẹ́ aláìní?’