ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́
Yẹra fún ojúsàájú (Di 16:18, 19; it-1 343 ¶5)
Wádìí ọ̀rọ̀ náà dáadáa (Di 17:4-6; it-2 511 ¶7)
Jẹ́ káwọn míì ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ẹjọ́ náà bá díjú (Di 17:8, 9; it-2 685 ¶6)
Àwọn alàgbà gbọ́dọ̀ rí i pé àwọn fi ìlànà yìí sílò tí wọ́n bá ń bójú tó ẹjọ́ kan nínú ìjọ.