July 5-11
DIUTARÓNÓMÌ 11-12
Orin 40 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bí Jèhófà Ṣe Fẹ́ Ká Máa Sin Òun”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Di 11:29—Ìgbà wo ló ṣeé ṣe kí ẹsẹ yìí nímùúṣẹ, kí ló sì ṣẹlẹ̀ nígbà yẹn? (it-1 925-926)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 11:1-12 (th ẹ̀kọ́ 2)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Fọ̀rọ̀ Ro Ara Ẹ Wò”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Túbọ̀ Já Fáfá—Máa Fọ̀rọ̀ Ro Ara Ẹ Wò.
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Ìyà—Jem 1:13. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 1)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 10 ¶8-12 àti àpótí 10A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 72 àti Àdúrà