August 1-7
1 ÀWỌN ỌBA 1-2
Orin 98 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ṣé O Máa Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àṣìṣe Ẹ?”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Ọb 2:37, 41-46—Kí la rí kọ́ látinú àṣìṣe Ṣíméì? (w05 7/1 30 ¶1)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 1:28-40 (th ẹ̀kọ́ 2)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o lò. Fún ẹni náà ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) kó o sì pe ẹni náà wá sípàdé. (th ẹ̀kọ́ 20)
Àsọyé: (5 min.) km 1/15 2 ¶1-3—Àkòrí: Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Tó Já Fáfá Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù. (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ohun Tó O Lè Fi Ṣe Àfojúsùn ní Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Tó Ń Bọ̀—Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere”: (7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Mú Kó O Ṣe Púpọ̀ Sí I—Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere.
“Ohun Tó O Lè Fi Ṣe Àfojúsùn ní Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Tó Ń Bọ̀—Máa Ṣèrànwọ́ Níbi Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ètò Ọlọ́run”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Mú Kó O Ṣe Púpọ̀ Sí I—Máa Ṣèrànwọ́ Níbi Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ètò Ọlọ́run.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 14
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 24 àti Àdúrà