August 22-28
1 ÀWỌN ỌBA 7
Orin 7 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Tá A Rí Kọ́ Lára Òpó Méjì”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Ọb 7:23—Kí la rí kọ́ lára ‘Òkun tí wọ́n fi irin ṣe’ tó wà nínú tẹ́ńpìlì? (it-1 263)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 7:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o lò. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Lẹ́yìn náà, fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì fi bá a ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì hàn án. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 06 kókó 6 àti Àwọn Kan Sọ Pé (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
“Àkànṣe Ìwàásù Láti Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lóṣù September”: (10 min.) Ìjíròrò. Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó iṣẹ́ yìí. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì—Sm 37:29. Sọ ètò tẹ́ ẹ ti ṣe fún àkànṣe ìwàásù náà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 17
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 13 àti Àdúrà