ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ọlọ́run Onídàájọ́ Òdodo Ni Jèhófà
Jèhófà ò gbàgbé ìwà ìkà tí Sọ́ọ̀lù hù sáwọn ará Gíbíónì (2Sa 21:1, 2)
Fàdákà àti wúrà ò lè mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ tó wà lórí Sọ́ọ̀lù àti agbo ilé rẹ̀ kúrò (Nọ 35:31, 33; 2Sa 21:3, 4)
Wọ́n pa méje lára àwọn ọmọ Sọ́ọ̀lù kí wọ́n lè mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ náà kúrò (2Sa 21:5, 6; it-1 932 ¶1)
Báwo ni Róòmù 12:19-21 ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ nígbà táwọn míì bá hùwà àìdáa sí wa?