Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ẹ́sírà ń ka Òfin Ọlọ́run fún àwọn èèyàn náà, ó sì ń yin Jèhófà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”

“Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”

Àwọn èèyàn náà kóra jọ láti gbọ́ bí Ẹ́sírà ṣe máa ka Òfin Ọlọ́run (Ne 8:1, 2; w13 10/15 21 ¶2; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ọjọ́ ayọ̀ lọjọ́ náà jẹ́ fáwọn èèyàn Jèhófà, kì í ṣe àsìkò láti máa kárí sọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ti dá sẹ́yìn (Ne 8:9, 11, 12)

Ìdùnnú Jèhófà jẹ́ ibi ààbò fáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ (Ne 8:10; w07 7/15 22 ¶9-10)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Láìka àwọn ìṣòro tí mò ń dojú kọ sí, àwọn nǹkan pàtó wo ni Jèhófà ti ṣe tó ń fún mi láyọ̀?’